CCC Hymn 526

by Celestial Hymn

1: Ona to ‘lorun ngba soro, Lati se ise Re, Ona Re enikan ko mo, Awamaridi ni. 2: Alaigbagbo won yio sina, Won ko ‘se Oluwa, Sugbon awa to gb’Oluwa gbo, A ki yio pofo laiye Amin