CCC Hymn 407

by Celestial Hymn

1: Wa pelu wa, sure fun wa, Oba Mimo, Se ri ‘bukun Re s’ori wa, Ka ma bisi, ka ma re si, ni Ijo Mimo, K’ Alleluya le j’orin wa. 2: Michael Mimo, gbe’da soke ka le bori, Gbogbo ota Ijo Mimo, K’o ko kehin le w’aiye mo lase Kristi, Ka le jumo ke Hossanah. 3: Ka boyun bi, kawon agan towo b’osun Ka ma rago, ka ma pose, Ka je seku, l’alafia ninu ayo nla, Ki iye, igbala je pin wa. Amin