CCC Hymn 261

by Celestial Hymn

Agbara na, Baba wa l’onfun, Agbara na, Baba wa l’onfun, Agbara na, Baba wa l’onfun, Enikeni to ba toro yio ri, Agbara to ju gbogbo agbara lo, Agbara to ju gbogbo agbara lo, Agbara nla, Agbara nla, Agbara, T’oju gbogbo agbara, L’o wa lodo Baba T’oju gbogbo agbara, L’o wa lodo Baba. Amin