CCC Hymn 205

by Celestial Hymn

1: Olorun Oba Imole Oba aiye raiye e, Ologo didan julo, Waju Eniti, Kekere ninu ese, Ki yio sunmo O, To nfi ife pe elese Lati r’ogo Re. 2: Awon ti o-fe lo npe, Awon to pe loyan a, Awon to yan lo se l’ogo, Laiye okunkun, Aiye nko ipe na, Nwon rin sinu okunkun, Lai fe ronupiwada, Labe iparun. 3: Ire t’ale logba Eden, Ronupiwada a, Wa si ibugbe Imole, Ibugbe ife, Nibiti Jesu njoba, Niwaju ite Baba, Elese ronupiwada, Ma ko ipe na. Amin