Ire

by BUKOLA BEKES

Ire/3* Nile mi ooo moo rire gba lowo oluwa... Ayo mi kun EBA mi joo Jesu ti soro mi dayo(2*) verse1: Hallelujah idemi ja hallelujah mo bori Ogun ese hallelujah moju asegun lo ororo Ayo on San nilewa. chorus.......(2*) verse2 Sugbon kan nbe laye mi emi ko femo lato niloo ire lotun ire losi he kowa mi ri oooo eledunmare maje ori wa gbabode.(2*). chorus.....(2*). hymn.... mosinmi le jesu ninu Igbi aye ire ire ire ire ....,..,,,,,, ire Ayo ire Ayo kowa sodo mi nitoripe iba nuje kosi loro mii moodupe call & rsp Gbani gbani gbani oo(4*) Gbani (4*). Gbagba gba ni to asaa ba Ogbeja keru o bori eni too Nija olori aye gbogbo...ooo Call: Nitori pe agan to kepe oluwa RSP: Ennnnnnnn..... Oromo gbejo ennnnnnmm afoju to kepe oluwa Nise loo riran Aro to keep oluwa kikia kia lodide koun Obirin Oni sun eje kepe jesu Isun eje gbe notori na kepeleda ree(2*) akuku she tire Olorun iyanu 3* aba o she oooo Mogbagbo olorun iyanu aba o see(2*) Toripe koma salagbara biire(2*) olorun iyanu (2*) Aba o see. (repeat). Aso one isoro re di petele Olorun alewi lese olorun adegboye. toripe koma salagbara biire re ..... 2* olorun iyanu (2*) repeat. Asoroko bi ogiri oke Awi mayewun Asoro ma taste asoro maybe oji lasaru oku ojo kerin dide ...