"Adara Fun O"
by Victorious Voices
Adara, Adara, Adara fun o o
Mama mi, eeee, Mama mi ooo/2x
Wa Jere Omo, O ni feyin ti sunkun Omo..
Mama mi eee, Mama mi ooo/2x
.Be mi o Je, Iya mi o ni Je, Be mi o mu, Iya mi ko ni mu, Ohun na lolutoju, Ninu ojo ninu erun, Iya mi sa lore mi, Momo riri re o, Mama mi ese oo, Mo se dansaki re, Mama mi o.
Adara, Adara, Adara fun o o
Mama mi, eeee, Mama mi ooo/2x
Wa Jere Omo, O ni feyin ti sunkun Omo
Mama mi eee, Mama mi ooo/2x
..Iya ni wura iyebiye, Ti a ko Le fowora, O loyun mi fosu mesan, O Pon mi fodun meta Aaah, Iya ni wura, Iyebiye ti a kole Fowo Ra.
Adara, Adara, Adara fun o o
Mama mi, eeee, Mama mi ooo/2x
Wa Jere Omo, O ni feyin ti sunkun Omo
Mama mi eee, Mama mi ooo/2x
...Bi n o jeun, Bi n o foso, Bi n o rabata, Gbogbo re Gbogbo re, Lori Mama mi lo dale, Orisa biya o si o.
Me le sai dupe ore re o/2x Iya mi
Adara, Adara, Adara fun o o
Mama mi, eeee, Mama mi ooo/2x
Wa Jere Omo, O ni feyin ti sunkun Omo
Mama mi eee, Mama mi ooo/2x
....Iya to n wa alaafia wa, Ese Iyebiye a pe yin lalabukun, Iya wa eku Ise/2x
Adara, Adara, Adara fun o o
Mama mi, eeee, Mama mi ooo/2x
Wa Jere Omo, O ni feyin ti sunkun Omo
Mama mi eee, Mama mi ooo/2x